Ísíkẹ́lì 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tó wà lókèèrè yóò kú pẹ̀lú àjàkálẹ̀-àrùn, àti ẹni tó wà nítòsí yóò ṣubú pẹ̀lú idà, ìyàn ni yóò pa ẹni tó bá ṣẹ́kù sílẹ̀. Báyìí ni n ó ṣe mú ìbínú gbígbóná mi wá sórí wọn.

Ísíkẹ́lì 6

Ísíkẹ́lì 6:6-13