Ísíkẹ́lì 5:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síbẹ̀ nínú ìwà búburú rẹ̀ ó ti ṣọ̀tẹ̀ si òfin àti ìlànà mi ju àwọn orílẹ̀ èdè àti àwọn ilẹ̀ tó yí i ká lọ. Ó ti kọ òfin mi sílẹ̀, kò sì pa ìlànà mi mọ́.

Ísíkẹ́lì 5

Ísíkẹ́lì 5:4-7