Ísíkẹ́lì 48:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ẹnu ọ̀nà ìlú ńlá náà ní àwa yóò fi orúkọ àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì pè. Àwọn ọ̀nà mẹ́tẹ̀ẹ̀ta ní ìhà àríwá ní yóò jẹ́ ọ̀nà tí Rúbẹ́nì, ọ̀nà tí Júdà ọ̀nà tí Léfì

Ísíkẹ́lì 48

Ísíkẹ́lì 48:27-35