Ísíkẹ́lì 48:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ísàkárì yóò ní ìpín kan: yóò jẹ́ ààlà agbégbé Símónì láti ìlà oòrùn sí ìwọ̀ oòrùn.

Ísíkẹ́lì 48

Ísíkẹ́lì 48:21-28