Ísíkẹ́lì 46:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò si pèsè ọrẹ-ẹbọ jíjẹ éfà fun ẹgbọrọ akọ màlúù, àti éfà kan fun àgbò kan, àti fun àwọn ọ̀dọ́-àgùntàn gẹ́gẹ́ bi èyí ti ipá rẹ̀ ká, àti hínì òróró kan fún éfà kan.

Ísíkẹ́lì 46

Ísíkẹ́lì 46:6-10