Ísíkẹ́lì 46:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní agbègbè inú ikọ̀ọ̀kan nínú àgbàlá náà ni ọwọ́ ilẹ̀ kan wà yíká wọn, a sì ṣe ibi ìdáná si abẹ́ ọwọ́ náà yípo.

Ísíkẹ́lì 46

Ísíkẹ́lì 46:20-24