Ísíkẹ́lì 45:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Láàárin ọjọ́ méje àṣè náà, tí ó bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kẹẹdógún oṣù kéje, òun yóò tún pèsè nǹkan bí ti tẹ́lẹ̀, fún ọrẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, ọrẹ ẹbọ sísun, ọrẹ ẹbọ jíjẹ pẹ̀lú òróró.

Ísíkẹ́lì 45

Ísíkẹ́lì 45:15-25