Ísíkẹ́lì 45:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣékélì ní kí o gba ogún gérà. Ogún ṣekeli pẹ̀lú ṣékélì márùndínlọ́gbọ̀n pẹ̀lú ṣékélì mẹ́ẹ̀dógún yóò jẹ́ mínà kan.

Ísíkẹ́lì 45

Ísíkẹ́lì 45:4-21