Ísíkẹ́lì 44:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún ọlọ̀tẹ̀ ilé Ísírẹ́lì pé, ‘Èyí yìí ni ohun tí Olúwa Ọba wí: Ìwà ìríra rẹ tí tó gẹ́ẹ́, ìwọ ilé Ísírẹ́lì!

Ísíkẹ́lì 44

Ísíkẹ́lì 44:5-16