Ísíkẹ́lì 44:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ko gbọdọ̀ fẹ́ opó ni ìyàwó, wọn kò sì gbọdọ̀ kọ ìyàwó wọn sílẹ̀; Wọ́n lè fẹ́ àwọn ọmọbìnrin ti kò tí i mọ ọkùnrin rí, tí ó sì jẹ́ ìran àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, tàbí kí wọn fẹ́ àwọn opó Àlùfáà.

Ísíkẹ́lì 44

Ísíkẹ́lì 44:15-27