Ísíkẹ́lì 44:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò gbọdọ̀ súnmọ́ ọ̀dọ̀ mi láti se ìránṣẹ́ fún mi, gẹ́gẹ́ bí àlùfáà tàbí súnmọ́ ìkankan nínú àwọn ohun mímọ́ mi tàbí ẹbọ mi mímọ́ jùlọ; wọn gbọdọ̀ gba ìtìjú ìwà ìríra wọn.

Ísíkẹ́lì 44

Ísíkẹ́lì 44:5-16