Ísíkẹ́lì 44:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ni ọkùnrin náà mú mi padà lọ sí ibi mímọ́, èyí tí ó kọjú sí ìhà ìlà oòrùn, ó sì wà ní títì.

Ísíkẹ́lì 44

Ísíkẹ́lì 44:1-3