Ísíkẹ́lì 43:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ni ìrusókè ẹ̀mí, ó sì mú mi lọ inú ilé ìdájọ́, sì kíyèsí ògo Olúwa kún inú ilé Ọlọ́run.

Ísíkẹ́lì 43

Ísíkẹ́lì 43:3-15