Ísíkẹ́lì 43:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Fún ọjọ́ méje, ìwọ ní láti pèsè akọ ewúrẹ́ kan lójoojúmọ́ fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀; Ìwọ yóò sì pèsè ọ̀dọ́ akọ màlúù àti àgbò láti inú agbo, méjèèjì yóò sì jẹ́ aláìlábàwọ́n.

Ísíkẹ́lì 43

Ísíkẹ́lì 43:15-27