Ísíkẹ́lì 43:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ibi ìdáná pẹpẹ náà jẹ́ igun mẹ́rin mẹ́rin lọ́gbọgba, ìgbọ̀nwọ́ méjìlá ní gígùn, o sì jẹ ìgbọ̀nwọ́ méjìlá ní fífẹ̀.

Ísíkẹ́lì 43

Ísíkẹ́lì 43:6-22