Ísíkẹ́lì 43:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìsàlẹ̀ rẹ̀ ni ilẹ̀ títí dé ìsàlẹ̀ igun rẹ̀, ó jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì ni gíga o sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ní fífẹ̀:

Ísíkẹ́lì 43

Ísíkẹ́lì 43:4-18