Ísíkẹ́lì 42:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ògiri kan wà ní ìta tí ó ṣe déédé pẹ̀lú àwọn yàrá àti ìta ilé ìdájọ́; a fàá gùn ní iwájú àwọn yàrá ní àádọ́ta ìgbọ̀nwọ́.

Ísíkẹ́lì 42

Ísíkẹ́lì 42:6-9