Ísíkẹ́lì 41:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O sì wọn gígùn inú yàrá ibi mímọ́; o sì jẹ ogún ìgbọ̀nwọ́, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ogún ìgbọ̀nwọ́ títí dé ìparí ìta ibi mímọ́. O sì sọ fún mi pé, “Èyí yìí ni ibi mímọ́ jùlọ.”

Ísíkẹ́lì 41

Ísíkẹ́lì 41:1-12