Ísíkẹ́lì 41:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ilẹ̀ sí agbègbè òkè ẹnu ọ̀nà, àwọn Kérúbù àti àwọn igi ọ̀pẹ ni wọ́n fín si ara ògiri ìta ibi mímọ́.

Ísíkẹ́lì 41

Ísíkẹ́lì 41:16-23