Ísíkẹ́lì 41:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìta gbangba lókè ìta ẹnu ọ̀nà inú ibi mímọ́ àti lára ògiri pẹ̀lú àlàfo tí kò ju ara wọn lọ yípo inú ìta ibi mímọ́

Ísíkẹ́lì 41

Ísíkẹ́lì 41:8-20