Ísíkẹ́lì 40:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó jẹ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́jọ ní jíjìn àtẹ́rígbà rẹ̀ sì jẹ ìgbọ̀nwọ́ méjì ní nínípọ̀n. Àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà kọjú sí tẹ́ḿpìlì.

Ísíkẹ́lì 40

Ísíkẹ́lì 40:5-14