Ísíkẹ́lì 40:47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wọn àgbàlá náà, ọgọ́rùn ún ìgbọ̀nwọ́ ni gígùn, ọgọ́rùn ún ìgbọ̀nwọ́ ni ìbú, igun mẹ́rin lọ́gbọọgba, àti pẹpẹ ti ń bẹ níwájú ilé náà.

Ísíkẹ́lì 40

Ísíkẹ́lì 40:37-49