Ísíkẹ́lì 40:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí fún mi pé, “yàrá yìí, tí iwájú rẹ̀ wà níhà gúsù, wà fún àwọn àlùfáà, àwọn ti n bojútó ilé náà.

Ísíkẹ́lì 40

Ísíkẹ́lì 40:42-49