Ísíkẹ́lì 40:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yàrá kan pẹ̀lú ilẹ̀kùn wà ní ẹ̀gbẹ́ àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà ní ọ̀kọ́ọ́kan ẹnu ọ̀nà inú, níbi tí wọn tí ń fọ àwọn ẹbọ sísun.

Ísíkẹ́lì 40

Ísíkẹ́lì 40:31-48