Ísíkẹ́lì 40:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(Àwọn àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà tí ó yí àgbàlá po jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹẹdọ́gbọ̀n ni fífẹ̀ àti ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún ni jínjìn).

Ísíkẹ́lì 40

Ísíkẹ́lì 40:27-36