Ísíkẹ́lì 40:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú mi lọ síbẹ̀, mo sì rí ọkùnrin kan tí ìrírí rẹ̀ dàbí ìrí bàba; ó dúró ni ẹnu ọ̀nà pẹ̀lú okùn aṣọ ọ̀gbọ̀ funfun àti ọ̀pá ìwọnlẹ̀ ní ọwọ́ rẹ̀.

Ísíkẹ́lì 40

Ísíkẹ́lì 40:1-4