Ísíkẹ́lì 40:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà, ó wọn gígùn àti ibú ẹnu ọ̀nà tí ó dojú kọ àríwá, à bá wọ àgbàlá.

Ísíkẹ́lì 40

Ísíkẹ́lì 40:10-25