Ísíkẹ́lì 40:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìjìnà ẹnu ọ̀nà àbáwọlé títí dé ìparí yàrá kéékèèkéé náà àti àwọn ìgbéró ògiri nínú ẹnu ọ̀nà ní a gbé dá jẹ́ àádọ́ta ìgbọ̀nwọ́.

Ísíkẹ́lì 40

Ísíkẹ́lì 40:6-16