Ísíkẹ́lì 39:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbi ìrúbọ tí mo ń múra kalẹ̀ fún yín, ẹ̀yin yóò jẹ ọ̀rá títí ẹ̀yin yóò fi jẹ àjẹkì, ẹ̀yin yóò sì mú ẹ̀jẹ̀ títí ẹ̀yin yóò fi yó.

Ísíkẹ́lì 39

Ísíkẹ́lì 39:10-27