Ísíkẹ́lì 37:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni àwọn orílẹ̀ èdè yóò mọ̀ pé, èmi Olúwa ṣọ Ísírẹ́lì di mímọ́, nígbà tí ibi mímọ́ mi bá wà ní àárin wọn títí ayérayé.’ ”

Ísíkẹ́lì 37

Ísíkẹ́lì 37:25-28