Ísíkẹ́lì 36:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ń ṣe àníyàn fún ọ, èmi yóò sì fi rere wọ̀ ọ́; àwa yóò tu ọ́, àwa yóò sì gbìn ọ́,

Ísíkẹ́lì 36

Ísíkẹ́lì 36:7-17