Ísíkẹ́lì 36:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò fún yín ni ọkàn tuntun, èmi yóò sì fi ẹmi tuntun sínú yín; Èmi yóò sì mú ọkàn òkúta kúrò nínú yín, èmi yóò sì fi ọkàn ẹran fún yín.

Ísíkẹ́lì 36

Ísíkẹ́lì 36:17-30