Ísíkẹ́lì 36:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Nítorí èmi yóò mú yín jáde kúrò ni àwọn orílẹ̀ èdè náà; Èmi yóò ṣà yín jọ kúrò ní gbogbo àwọn ìlú náà; Èmi yóò sì mú yín padà sí ilẹ̀ ẹ̀yin tìkarayín.

Ísíkẹ́lì 36

Ísíkẹ́lì 36:15-34