Ísíkẹ́lì 36:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo tú wọn ká sí àárin àwọn orílẹ̀ èdè, a sì fọ́n wọn ká sí àwọn ìlú; mo ṣe ìdájọ́ wọn gẹ́gẹ́ bí ìwà àti ìṣe wọn.

Ísíkẹ́lì 36

Ísíkẹ́lì 36:9-21