Ísíkẹ́lì 36:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọmọ ènìyàn, sọ tẹ́lẹ̀ sí àwọn òkè gíga Ísírẹ́lì kí o sì wí pé, ‘Ẹ̀yin òkè gíga Ísírẹ́lì gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa.

Ísíkẹ́lì 36

Ísíkẹ́lì 36:1-11