Ísíkẹ́lì 35:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò fi àwọn tí a pa kún orí òkè rẹ: àwọn tí a fi idà pa yóò ṣubú ní orí òkè rẹ, àti ní àárin àwọn òkè rẹ.

Ísíkẹ́lì 35

Ísíkẹ́lì 35:2-10