Ísíkẹ́lì 35:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí náà bi mo ti wà láàyè, ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí, èmi yóò fi ọ kalẹ̀ fún ìtàjẹ̀ sílẹ̀, ìtàjẹ̀ sílẹ̀ yóò sì lépa rẹ. Níwọ̀n ìgbà tí ìwọ kò ti korìíra ìtàjẹ̀-sílẹ̀, ìtàjẹ̀-sílẹ̀ yóò sì lépa rẹ.

Ísíkẹ́lì 35

Ísíkẹ́lì 35:1-15