Ísíkẹ́lì 35:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o sì sọ wí pé: ‘Èyí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: Èmí lòdì sí ọ, òkè Séírì, Èmi yóò sì na ọwọ́ mi síta ní ìlòdì sí ọ, èmi yóò sì mú kí o di ahoro.

Ísíkẹ́lì 35

Ísíkẹ́lì 35:1-4