Ísíkẹ́lì 34:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ jẹ wàrà. O sì wọ aṣọ olówùú sí ara rẹ, o sì ń pa ẹran tí ó wù ọ́, ṣùgbọ́n ìwọ kò tọ́jú agbo ẹran.

Ísíkẹ́lì 34

Ísíkẹ́lì 34:1-13