Ísíkẹ́lì 33:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọmọ ènìyàn, èmi fi ọ ṣe alóre fún ilé Ísírẹ́lì; nítorí náà gbọ́ ọ̀rọ̀ tí mo sọ, kí o sì fún wọn ni ìkìlọ̀ láti ọ̀dọ̀ mi.

Ísíkẹ́lì 33

Ísíkẹ́lì 33:1-17