Ísíkẹ́lì 33:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní tìrẹ, ọmọ ènìyàn, àwọn ènìyàn ìlú n sọ̀rọ̀ nípa rẹ ní ẹ̀gbẹ́ ògiri àti ní ẹnu ọ̀nà ilé wọn, wọ́n ń sọ sí ara wọn wí pé, ‘Ẹ wá gbọ́ iṣẹ́ ti a ran láti ọ̀dọ̀ Olúwa wá.’

Ísíkẹ́lì 33

Ísíkẹ́lì 33:25-33