Ísíkẹ́lì 33:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ karùn ún oṣù kẹ́wàá, ọdún kejìlá ìkólọ wa, ọkùnrin kan tí ó sá kúrò ni Jerúsálẹ́mù wá sọ́dọ̀ mi, ó sì wí pé, “Ìlú ńlá náà ti ṣubú!”

Ísíkẹ́lì 33

Ísíkẹ́lì 33:13-30