Ísíkẹ́lì 33:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ó bá mu ògo padà, tí o sì da ohun tí o ti jí gbé padà, tí ó sì tẹ̀lé òfin tí ó ń fún ni ní ìyè, tí kò sì ṣe búburú, òun yóò yè dandan; òun kì yóò kú.

Ísíkẹ́lì 33

Ísíkẹ́lì 33:6-24