Ísíkẹ́lì 32:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ìmọ́lẹ̀ títàn ní ojú ọ̀runni èmi yóò mú ṣókùnkùn lórí rẹ;èmi yóò mú òkùnkùn wá sórí ilẹ rẹ,ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí

Ísíkẹ́lì 32

Ísíkẹ́lì 32:5-15