Ísíkẹ́lì 32:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀jẹ̀ rẹ ti ń ṣàn ní èmi yóò sì fi rin ilẹ̀ náàgbogbo ọ̀nà sí orí àwọn òkè gíga,àwọn àlàfo jínjìn ní wọn yóò kún fún ẹran ara rẹ.

Ísíkẹ́lì 32

Ísíkẹ́lì 32:1-9