Ísíkẹ́lì 32:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Fáráò, òun àti gbogbo jagunjagun rẹ̀ óò rí wọn, a yóò sì tù ú nínú nítorí gbogbo ìjọ rẹ̀ tí a fi idà pa, ní Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.

Ísíkẹ́lì 32

Ísíkẹ́lì 32:27-32