Ísíkẹ́lì 32:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí yìí ni ẹkún tí a óò sun fún un. Àwọn ọmọbìnrin orílẹ̀ èdè yóò sun ún; nítorí Éjíbítì àti gbogbo ìjọ rẹ, wọn yóò sun ún, ní Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.”

Ísíkẹ́lì 32

Ísíkẹ́lì 32:9-24