Ísíkẹ́lì 32:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ní ọjọ́ kìn-ín-ní, oṣù kejìlá, ọdún kejìlá, ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá:

2. “Ọmọ ènìyàn, ṣe ìpohùnréré ẹkún nítorí Fáráò Ọba Éjíbítì kí o sì wí fún un:“ ‘Ìwọ dàbí kìnnìún láàárin àwọnorílẹ̀ èdè náà;ìwọ dàbí ohun abanilẹ́rù inú àwọn okun to ń lọkáàkiri inú àwọn odò rẹ,ìwọ fi ẹsẹ rẹ tẹ omiláti mú kí àwọn odò ní ẹrẹ̀.

Ísíkẹ́lì 32