Ísíkẹ́lì 31:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Omi mú un dàgbà sókè:orísun omi tí ó jìnlẹ̀ mú kí o dàgbà sókè;àwọn odo rẹ̀ ń sàn yí ìdí rẹ̀ ká,ó sì rán ìṣàn omi rẹ̀ sí gbogbo igi orí pápá.

Ísíkẹ́lì 31

Ísíkẹ́lì 31:3-9