Ísíkẹ́lì 31:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tí ó ń gbé ní abẹ́ ìjì rẹ̀, àwọn àjòjì rẹ ní àárin àwọn orílẹ̀ èdè náà, ti lọ sí ìsàlẹ̀ isà òkú pẹ̀lú rẹ̀, ní dídárapọ̀ mọ́ àwọn tí a fi idà pa.

Ísíkẹ́lì 31

Ísíkẹ́lì 31:9-18